Kurani Alaponle - Yoruba Quran 4+

Kurani Alaponle ede Yoruba

MP3Quran

Designed for iPad

    • Free

Screenshots

Description

Itunmo awon oro Kurani Alaponle ti o se gba ra lee ni ede Yoruba pelu ki kaa

Kurani Alaponle ede Yoruba
Itunmo awon oro Kurani Alaponle ti o se gba ra lee ni ede Yoruba pelu ki kaa ati ti tuu pelu ohun.

O le gbaa ohun elo yi ka le, o si tun le maa woo oju ewe Kurani Alaponle ni ede (Yoruba) pelu onaa ti o rorun ju lo, ati pelu onaa ti o se oju loin ti o si daa ra, e yi awon akose-monse nkan yiya ati i se Kurani lo so ni agabye se fi ko.


E yi je ise agbese ti o je oofee ti ko si ni ipolongo ninu, ti o wa fun gbobgbo fun la ti maa loo, ni ti to ri Olohun.

***Awon nkan esa ohun elo***
- O rorun la ti lo: O si tun ni fonti ti o mon ni won ba ti o si ni orisis agbara ti on te si waju.
- Iwadi yara-yara ninu awon oro Kurani Alaponle ati ninu awon oruko ogba oro ati eka-eka Kurani.
- Ki ka Kurani: Je igbadun ki ka Kurani Alaponle ti a da ko lati ibi ti o se gbaa ra le ati e yi ti a se lo so lo na ti o daa raa.
- Awon itumon Kurani Alaponle: Gbo Kurani Alaponle ni ede re peu bi awon itumon re se ti wa ni ede Yoruba.
- Awon Ede orisisi: Maa lo ohun elo yi pelu ede re ta bi ede miran ti o ni fe si laa ti maa wo Kurani.
- Ki ka Kurani: Maa gbo ki ka Kurani Alaponle pelu ohun awon oluka Kurani to gba ju mo ati awon ti won man kaa Kurani pelu ohun dun-dun.
- Ti tumon Kurani pelu ohun: Gbigbo itumon Kurani Alaponle pelu ohun ni ede Yoruba.
- Ti tan ohun ti o loo si waju: Ti tan ohun yi o fun ni awon anfani agbara ti o lo si waju gege bi pi paara e yi ti yi o ron oo lo wo laa ti ha Kurani Alaponle.
- Ālā: Fi fi awon āmi ibi a ti ri awon anfani ati sise idari won, ki o le rọrun la ti dari si awon aye lati duro ni awon amin (Āyah) ko kon.
- Nkan ti a yan laa yo: Fi fi awon orisis amin (Āyah) ti a yan laa yo si be, ki o la sa re pa da si be ti o ba ya.
- Fi fi irori ye si be: Fi fi irori ati ironu si be laa rin ki ka Al-Kurani tabi ni igba ti a ban ka itumo re.
- pin pin nkan pelu elomiran: Pin pin awon ami (Āyah) tabi awon itumon re pelu awon ọrẹ rẹ lati ibi awon ohun a tẹle ati awon ona ayelujara.
- Mi mo nkan ni o na aara: Sise a sa yan awon aawọ orisisi ati awon nkan yoro-yoro ti o se oju loin, ati mi mo nkan ni ti igba lode ti a mu ni ibi olaju awon elede Yoruba.

App Privacy

The developer, MP3Quran, indicated that the app’s privacy practices may include handling of data as described below. For more information, see the developer's privacy policy.

Data Not Linked to You

The following data may be collected but it is not linked to your identity:

  • Diagnostics

Privacy practices may vary, for example, based on the features you use or your age. Learn More

More By This Developer

MP3Quran
Education
Quran with Urdu translation.
Books
مصحف التلاوة حفص Telawa Hafs
Reference
Al Fatiha | الفاتحة
Education
Amharic Quran المصحف الأمهري
Books
مصحف التلاوة ورش Telawa Warsh
Reference

You Might Also Like

Oro Yoruba
Education
Smart Yoruba Dictionary
Education
English To Yoruba Translation
Education
Yoruba-English Dictionary
Reference
English to Yoruba Translator.
Education
Yoruba Bible (Bibeli Mimo)
Reference